logo
HOME | MUSIC | VIDEO | ENTERTAINMENT | NEWS | MIXTAPE | FUNNY POSTS | EDUCATION | SPORTS | OTHERS


PROMOTE MUSIC/VIDEO | ADVERTISE WITH US 

« | »

[Lyrics] Jubet – Ogun Idile Ni

    Intro 

Jubet, msn, File Fun Mio kin Je Ori, J U,
Bridge

Shagba To ti fo, ogun Idile Ni
Teba ti ja bo ogun Idile Ni
Aja yin gan pa ogun Idile Ni
Komale gbera ogun Idile Ni
Awon were kan won fe mo le mi
Won ti Gba gbe pe ogun Idile Ni
Mofi ye won pe ogun Idile Ni
Won ti Gba gbe pe ogun Idile Ni. 2x

verse 1

Mo Mo bi osele Je ti oti fi kole ti oti fi sile Mo fe kolo Gba adura ole Je ogun Idile

[Ogun Idile Ni]

Teba fail nibibai ema fi ayA Gba le
Teba fi oju di mi emafiaya wole
Emi ru erin lori motun tere mon le Emi diju wo inu club Ni moseun teyan mole
(ogun idile ni ahh ogun idile ni ema bawi ogun idile ni ehhh)

Asan ni aye ejekama sorawa
kadiju kase bi enitoku kawo enitoma sukun wa

Nigba ti moko file fun awon eyen fe ma buwa

Sugbon nisin mo ti ko ogun idile awon were tin wa oju wa
(ogun idile ni ema bawi ogun idile ni ehhhh

Moti ri obinrin tole magun sile fun aja
Moti sofun lagbaja kofun alaja ni iborun re komaje kaja
tori lajalaja loba segi segi Moti kuro ni aro Moti gba ile si iyana opaja
(ogun idile ni)

Shara sawon tan gbadura fun mi tan komi bi won seun love lori [love]

Lori facebook toye kan send hy nise na send xup xup
Moni aso yin toba ya ni kemakolo shop
boya ema ri tailor toma ran tabi awon ejika ni shop
(ogun idile ni)
HOOK
ikun le abiamon esanu ahje oo
atiso nu gan anlo ilu aje oo
Ebere mole ke ma jo inubimi king ogbodo mo si ma feature king baddo
Mosun magun 2X
Laye mio ni lu magun

Choruz
Ogun idile ahhh

Ogun idile ni emabawi Ogun idile ni yehhh 2x

Oun hustle, oun jise, sack leter aisan se , o fail exam odo jue fun awon ota mi Ogun idile ni ahhh
Ogun idile ni emabawi Ogun ni ehhh 2X

Bridge

Verse 2
Won ni emi ni jubet awon ni badest, Won ni emi ni rapper awon ni singer ahhhh
Ope mi ni mola moni mogalant, Ope mi ni solider moni mo gayant awa lan so Obe awon solider ant seti gbo se ti duo
Seti gbo gbo gbo
Orin tan fe gan moti ko ko ko
Awa landaluru igi woroko tin ba tin shoro ke de ma ko gbo

Hook

Choruz
Bridge
Outro jubet
File fun mio kin je ori msn ju dj shexy mix.
Share This Post on Facebook!

[Lyrics] Boss TI – Jeje Laye

[Lyrics] Lil Expo ft. Black Metal – Tarkwa Ye D3w

[Lyrics] Adeola – Yabaleft Anthem

[Lyrics] Lil Mhizzy – Parkwell

[Lyrics] Presido ft. Lil Mhizzy – Do You Well

[Lyrics] Hot-Ice – DonDADAADVERTISE ON   

Have Something Interesting/Informative you want us to Post on ? Send to info@jdtrendz.com


Like Us On Facebook

Follow Us On Twitter

Join our BBM Channel

Posted by kolade On May 18, 2017

Categories: Lyrics

URL
HTML
BB CODE
No Comments Yet

Leave a Reply

Your Name:

Your Message:

NOTE:- After Dropping your comment, Wait for few minutes, your comments will appear after Moderation!!
Go Back To The Top


« | »